Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ August 16
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ AUGUST 16
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: 2 Àwọn Ọba 1-4
No. 1: 2 Àwọn Ọba 1:1-10
No. 2: Ìdí Tí Àwọn Nǹkan Tara Kò Fi Lè Fúnni Ní Ojúlówó Ìtẹ́lọ́rùn (Oníw. 5:10)
No. 3: Iná Ṣàpẹẹrẹ Ìparun Yán-ányán-án (td 16B)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
10 min: Ran Ẹni Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́wọ́ Kó Lè Di Akéde. Àsọyé tá a gbé ka ìwé A Ṣètò Wa, ojú ìwé 79, ìpínrọ̀ 1 sí ìparí ojú ìwé 80.
20 min: “O Lè Jẹ́rìí Láìjẹ́-bí-Àṣà!”—Apá Kejì. Ẹ jíròrò ìpínrọ̀ 9 sí 13 àti àpótí tó wà lójú ìwé 3 lọ́nà ìbéèrè àti ìdáhùn.