Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ August 23
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ AUGUST 23
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: 2 Àwọn Ọba 5-8
No. 1: 2 Àwọn Ọba 6:8-19
No. 2: Àkàwé Ọlọ́rọ̀ àti Lásárù Kì Í Ṣe Ẹ̀rí Ìdálóró Ayérayé (td 16D)
No. 3: Báwo Ni Ẹnì Kan Ṣe Lè Sọ Ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ Ara Di Ọlọ́run? (Fílí. 3:18, 19)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
30 min: “Àpéjọ Àgbègbè Jẹ́ Àkókò Ìjọsìn Aláyọ̀.” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Bí àkókò bá ṣe wà sí, jíròrò àwọn ìránnilétí tó kan ìjọ yín gbọ̀ngbọ̀n látinú “Àwọn Ohun Tó Yẹ Ká Fi Sọ́kàn Nípa Àpéjọ Àgbègbè,” tó wà lójú ìwé 6.