ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 11/13 ojú ìwé 3
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ November 25

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ November 25
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2013
  • Ìsọ̀rí
  • Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ NOVEMBER 25
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2013
km 11/13 ojú ìwé 3

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ November 25

Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ NOVEMBER 25

Orin 122 àti Àdúrà

□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:

jl Ẹ̀kọ́ 11 sí 13 (30 min.)

□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:

Bíbélì kíkà: Jákọ́bù 1-5 (10 min.)

No. 1: Jákọ́bù 1:22–2:13 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

No. 2: Bí Ìfẹ́ Ṣe Ń Borí Ìbẹ̀rù—1 Jòh. 4:16-18 (5 min.)

No. 3: Kí Ló Ń Fa Ikú?—td 24A (5 min.)

□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:

Orin 95

10 min: Àwọn Àbá Tá A Lè Lò Láti Fi Ìwé Ìròyìn Lọni Lóṣù December. Ìjíròrò. Fi ààbọ̀ ìṣẹ́jú sí ìṣẹ́jú kan sọ ìdí táwọn èèyàn fi máa nífẹ̀ẹ́ sí àwọn ìwé ìròyìn náà ní ìpínlẹ̀ ìwàásù yín. Lẹ́yìn náà, lo àwọn àpilẹ̀kọ tó dá lórí àkòrí Ilé Ìṣọ́ December 1, kó o sì ní kí àwọn ará sọ àwọn ìbéèrè tó lè mú kí àwọn èèyàn nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ wọn. Lẹ́yìn náà, kí wọ́n sọ ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tí wọ́n lè fi ti ọ̀rọ̀ wọn lẹ́yìn. Ohun kan náà ni kó o ṣe nípa àwọn àpilẹ̀kọ tó dá lórí àkòrí Jí! November–December 2013. Bí àkókò bá ṣì wà, ẹ tún lè jíròrò àpilẹ̀kọ mìíràn nínú ọ̀kan lára ìwé ìròyìn méjèèjì. Ṣe àṣefihàn bá a ṣe lè fi ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ìwé ìròyìn náà lọni.

10 min: Báwo Ló Ṣe Yẹ Kó O Dáhùn? Àsọyé tá a gbé ka ìwé Jàǹfààní, ojú ìwé 69, ìpínrọ̀ 1 sí 5. Ṣe àṣefihàn bí akéde kan ṣe dá ẹni tó ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lóhùn nígbà tí akẹ́kọ̀ọ́ náà fẹ́ ṣe ìpinnu ara ẹni. Kí akẹ́kọ̀ọ́ náà béèrè lọ́wọ́ akéde náà pé, “Kí lo máa ṣe tó bá jẹ́ pé ìwọ lo wà nírú ipò tí mo wà yìí?”

10 min: “Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ń Sa Agbára.” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Sọ ọjọ́ tẹ́ ẹ máa lọ sí àpéjọ àkànṣe yín, tẹ́ ẹ bá ti mọ̀ ọ́n.

Orin 45 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́