Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2013
- Iye Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà: 91 
- Iye Orílẹ̀-Èdè Tó Ròyìn: 239 
- Àròpọ̀ Iye Ìjọ: 113,823 
- Àwọn Tó Wá Síbi Ìrántí Ikú Kristi Kárí Ayé: 19,241,252 
- Àwọn Tó Jẹ Ohun Ìṣàpẹẹrẹ Kárí Ayé: 13,204 
- Góńgó Akéde: 7,965,954 
- Ìpíndọ́gba Akéde Tó Ń Wàásù Lóṣooṣù: 7,698,377 
- Iye Tá A Fi Pọ̀ Ju Ti Ọdún 2012: 159,383 
- Àròpọ̀ Iye Àwọn Tó Ṣèrìbọmi: 277,344 
- Ìpíndọ́gba Aṣáájú-Ọ̀nà Olùrànlọ́wọ́ Lóṣooṣù: 496,089 
- Ìpíndọ́gba Aṣáájú-Ọ̀nà Déédéé Lóṣooṣù: 1,025,677 
- Àròpọ̀ Wákàtí Tá A Lò Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù: 1,841,180,235 
- Ìpíndọ́gba Àwọn Tá À Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lóṣooṣù: 9,254,963 
Lọ́dún iṣẹ́ ìsìn 2013, àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ná nǹkan bí igba [200] mílíọ̀nù owó dọ́là ti ilẹ̀ Amẹ́ríkà láti bójú tó àwọn aṣáájú-ọ̀nà àkànṣe, àwọn míṣọ́nnárì àtàwọn alábòójútó arìnrìn-àjò lẹ́nu iṣẹ́ wọn.
Bákan náà, kárí ayé, iye àwọn tó ń ṣiṣẹ́ láwọn ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjìlélógún, ọgọ́rùn-ún méje àti mọ́kàndínlógún [22,719]. Wọ́n wà lára Àwọn Tó Ń Ṣe Àkànṣe Iṣẹ́ Ìsìn Alákòókò Kíkún Lára Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà.