ÀWỌN ONÍDÀÁJỌ́
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  - 
- Àwọn tí Júdà àti Síméónì ṣẹ́gun (1-20) 
- Àwọn ará Jébúsì ò kúrò ní Jerúsálẹ́mù (21) 
- Jósẹ́fù gba Bẹ́tẹ́lì (22-26) 
- Wọn ò lé àwọn ọmọ Kénáánì kúrò tán (27-36) 
 
-  2  
-  3  - 
- Jèhófà dán Ísírẹ́lì wò (1-6) 
- Ótíníẹ́lì, onídàájọ́ àkọ́kọ́ (7-11) 
- Éhúdù onídàájọ́ pa Ẹ́gílónì, ọba tó sanra (12-30) 
- Ṣámúgárì onídàájọ́ (31) 
 
-  4  - 
- Jábínì ọba Kénáánì fìyà jẹ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì (1-3) 
- Dèbórà wòlíì obìnrin àti Bárákì onídàájọ́ (4-16) 
- Jáẹ́lì pa Sísérà olórí ogun (17-24) 
 
-  5  
-  6  - 
- Mídíánì fìyà jẹ Ísírẹ́lì (1-10) 
- Áńgẹ́lì kan fi dá Gídíónì Onídàájọ́ lójú pé Jèhófà máa ràn án lọ́wọ́ (11-24) 
- Gídíónì wó pẹpẹ Báálì lulẹ̀ (25-32) 
- Ẹ̀mí Ọlọ́run bà lé Gídíónì (33-35) 
- Ó fi ìṣùpọ̀ irun àgùntàn wádìí ọ̀rọ̀ (36-40) 
 
-  7  
-  8  - 
- Àwọn èèyàn Éfúrémù bínú sí Gídíónì (1-3) 
- Wọ́n lé àwọn ọba Mídíánì mú, wọ́n sì pa wọ́n (4-21) 
- Gídíónì ò gbà kí wọ́n fi òun jọba (22-27) 
- Àkópọ̀ ìtàn ìgbésí ayé Gídíónì (28-35) 
 
-  9  - 
- Ábímélékì jọba ní Ṣékémù (1-6) 
- Jótámù ṣe àkàwé (7-21) 
- Ìjọba Ábímélékì ni àwọn èèyàn lára (22-33) 
- Ábímélékì gbógun ja Ṣékémù (34-49) 
- Obìnrin kan ṣe Ábímélékì léṣe, ó sì kú (50-57) 
 
- 10  - 
- Tólà àti Jáírì onídàájọ́ (1-5) 
- Ísírẹ́lì ṣọ̀tẹ̀, ó sì ronú pìwà dà (6-16) 
- Àwọn ọmọ Ámónì halẹ̀ mọ́ Ísírẹ́lì (17, 18) 
 
- 11  - 
- Wọ́n lé Jẹ́fútà onídàájọ́ jáde, àmọ́ wọ́n sọ ọ́ di olórí nígbà tó yá (1-11) 
- Jẹ́fútà bá àwọn ọmọ Ámónì sọ̀rọ̀ (12-28) 
- Ẹ̀jẹ́ tí Jẹ́fútà jẹ́ àti ọmọbìnrin rẹ̀ (29-40) 
 
- 12  
- 13  
- 14  - 
- Sámúsìn onídàájọ́ fẹ́ fi ọmọ Filísínì ṣe aya (1-4) 
- Ẹ̀mí Jèhófà mú kí Sámúsìn pa kìnnìún (5-9) 
- Sámúsìn pa àlọ́ níbi ìgbéyàwó (10-19) 
- Wọ́n fún ọkùnrin míì ní ìyàwó Sámúsìn (20) 
 
- 15  
- 16  
- 17  
- 18  
- 19  
- 20  
- 21