RÚÙTÙ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  - 
- Élímélékì àti ìdílé rẹ̀ kó lọ sí Móábù (1, 2) 
- Náómì, Ọ́pà àti Rúùtù di opó (3-6) 
- Rúùtù kò fi Náómì àti Jèhófà sílẹ̀ (7-17) 
- Náómì pa dà sí Bẹ́tílẹ́hẹ́mù, Rúùtù tẹ̀ lé e (18-22) 
 
-  2  - 
- Rúùtù pèéṣẹ́ ní oko Bóásì (1-3) 
- Rúùtù àti Bóásì pàdé (4-16) 
- Rúùtù sọ fún Náómì bí Bóásì ṣe ṣojúure sí òun (17-23) 
 
-  3  - 
- Náómì sọ ohun tí Rúùtù máa ṣe (1-4) 
- Rúùtù àti Bóásì ní ibi ìpakà (5-15) 
- Rúùtù pa dà sọ́dọ̀ Náómì (16-18) 
 
-  4