JÓNÀ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  - 
- Jónà fẹ́ sá fún Jèhófà (1-3) 
- Jèhófà mú kí ìjì kan tó lágbára jà (4-6) 
- Jónà ló fa wàhálà tó dé bá wọn (7-13) 
- Wọ́n ju Jónà sínú òkun tó ń ru gùdù (14-16) 
- Ẹja ńlá kan gbé Jónà mì (17) 
 
-  2  
-  3  - 
- Jónà ṣègbọràn sí Ọlọ́run, ó sì lọ sí Nínéfè (1-4) 
- Ọ̀rọ̀ Jónà mú kí àwọn ará Nínéfè ronú pìwà dà (5-9) 
- Ọlọ́run pinnu pé òun ò ní pa Nínéfè run (10) 
 
-  4