Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí:
- 1. Kí nìdí tó fi yẹ ká jẹ́ kígbàgbọ́ wa lágbára báyìí? (Héb. 10:39) 
- 2. Báwo la ṣe lè “rí” Jèhófà bó tiẹ̀ jẹ́ pé a ò lè rí i lójúkojú? (Héb. 11:27) 
- 3. Kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì ká máa ṣàyẹ̀wò àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì? (Róòmù 10:17) 
- 4. Báwo ni ẹ̀mí mímọ́ ṣe lè jẹ́ ká nígbàgbọ́? (Lúùkù 11:13; Gál. 5:22) 
- 5. Báwo la ṣe lè ran àwọn míì lọ́wọ́ kí ìgbàgbọ́ wọn lè lágbára? (1 Tẹs. 2:7, 8) 
- 6. Kí nìdí tó fi yẹ ká máa “tẹjú mọ́ . . . Olórí Aṣojú àti Aláṣepé ìgbàgbọ́ wa”? (Héb. 12:2, 3) 
© 2021 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
CA-brpgm22-YR