Saturday
“Ẹ máa mú sùúrù fún gbogbo èèyàn”—1 Tẹsalóníkà 5:14
Àárọ̀
- 9:20 Fídíò Orin 
- 9:30 Orin 58 àti Àdúrà 
- 9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: ‘À Ń Dámọ̀ràn Ara Wa Bí Òjíṣẹ́ Ọlọ́run . . . Bá A Ṣe Ń Mú Sùúrù’ - • Tá A Bá Ń Wàásù (Ìṣe 26:29; 2 Kọ́ríńtì 6:4, 6) 
- • Tá A Bá Ń Kọ́ni (Jòhánù 16:12) 
- • Tá A Bá Ń Fún Ara Wa Níṣìírí (1 Tẹsalóníkà 5:11) 
- • Tá A Bá Jẹ́ Alàgbà (2 Tímótì 4:2) 
 
- 10:30 Ẹ Máa Mú Sùúrù Fáwọn Èèyàn Bí Jèhófà Ṣe Ń Mú Sùúrù fún Yín! (Mátíù 7:1, 2; 18:23-35) 
- 10:50 Orin 138 àti Ìfilọ̀ 
- 11:00 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: ‘Ẹ Ní Sùúrù, Kí Ẹ sì Máa Fara Dà Á fún Ara Yín Nínú Ìfẹ́’ - • Àwọn Mọ̀lẹ́bí Wa tí Kò Sin Jèhófà (Kólósè 4:6) 
- • Ọkọ Tàbí Aya Rẹ (Òwe 19:11) 
- • Àwọn Ọmọ Rẹ (2 Tímótì 3:14) 
- • Àwọn Àgbàlagbà Tàbí Àwọn tí Ara Wọn Ò Le Nínú Ìdílé (Hébérù 13:16) 
 
- 11:45 ÌRÌBỌMI: Sùúrù Jèhófà Máa Jẹ́ Ká Rí Ìgbàlà! (2 Pétérù 3:13-15) 
- 12:15 Orin 75 àti Àkókò Ìsinmi 
Ọ̀sán
- 1:35 Fídíò Orin 
- 1:45 Orin 106 
- 1:50 Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Ṣọ́ra fún Ìgbádùn Ojú Ẹsẹ̀? (1 Tẹsalóníkà 4:3-5; 1 Jòhánù 2:17) 
- 2:15 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: ‘Ó Sàn Kéèyàn Ní Sùúrù Ju Pé Kó Máa Gbéra Ga’ - • Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ébẹ́lì, Má Tẹ̀ Lé ti Ádámù (Oníwàásù 7:8) 
- • Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jékọ́bù, Má Tẹ̀ Lé ti Ísọ̀ (Hébérù 12:16) 
- • Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Mósè, Má Tẹ̀ Lé ti Kórà (Nọ́ńbà 16:9, 10) 
- • Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Sámúẹ́lì, Má Tẹ̀ Lé ti Sọ́ọ̀lù (1 Sámúẹ́lì 15:22) 
- • Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jónátánì, Má Tẹ̀ Lé ti Ábúsálómù (1 Sámúẹ́lì 23:16-18) 
 
- 3:15 Orin 87 àti Ìfilọ̀ 
- 3:25 FÍDÍÒ: “Fi Ọ̀nà Rẹ Lé Jèhófà Lọ́wọ́”—Apá 1 (Sáàmù 37:5) 
- 3:55 “Nígbà Tí Wọ́n Ń Ṣe Inúnibíni sí Wa, À Ń Fara Dà Á Pẹ̀lú Sùúrù” (1 Kọ́ríńtì 4:12; Róòmù 12:14, 21) 
- 4:30 Orin 79 àti Àdúrà Ìparí