Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí:
- 1. Báwo la ṣe lè ‘máa retí Jèhófà’? (Sm. 130:5, 6) 
- 2. Báwo la ṣe lè máa retí Jèhófà nígbà ìṣòro? (Háb. 2:3, 4; 2 Tím. 4:2; Lúùkù 2:36-38) 
- 3. Báwo la ṣe lè máa fọgbọ́n lo àkókò wa bá a ṣe ń retí ọjọ́ Jèhófà? (2 Pét. 3:11-13) 
- 4. Kí nìdí tó fi yẹ kọ́kàn wa balẹ̀ bá a ṣe ń retí Jèhófà lásìkò tá a bá dojú kọ ìṣòro? (Sm. 62:1, 2, 8, 10; 68:6; 130:2-4) 
- 5. Kí ló yẹ ká ṣe ká lè gba ‘èrè tó wà fún olódodo’? (Sm. 58:11) 
© 2023 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
CA-copgm24-YR