‘Máa Retí Jèhófà’
Àárọ̀
- 9:30 Ohùn Orin 
- 9:40 Orin 88 àti Àdúrà 
- 9:50 Báwo La Ṣe Lè Máa “Retí Jèhófà”? 
- 10:05 Àpínsọ Àsọyé: Fara Wé Àwọn Tó Retí Jèhófà - • Hábákúkù 
- • Jòhánù 
- • Ánà 
 
- 11:05 Orin 142 àti Ìfilọ̀ 
- 11:15 Kí Ló Ń Dá Ẹ Dúró Láti Ṣe Púpọ̀ Sí I? 
- 11:30 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi 
- 12:00 Orin 28 
Ọ̀sán
- 1:10 Ohùn Orin 
- 1:20 Orin 54 àti Àdúrà 
- 1:30 Àsọyé fún Gbogbo Èèyàn: Kí Nìdí Tó Fi Ṣe Pàtàkì Pé Ká Ní Sùúrù? 
- 2:00 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ 
- 2:30 Orin 143 àti Ìfilọ̀ 
- 2:40 Àpínsọ Àsọyé: Máa Retí Jèhófà . . . - • Tó Bá Ń Ṣe Ẹ́ Bíi Pé O Dá Wà 
- • Tó O Bá Ṣàṣìṣe 
- • Tí Nǹkan Bá Ń Lọ Dáadáa Fáwọn Ẹni Burúkú 
 
- 3:40 “Èrè Wà fún Olódodo” 
- 4:15 Orin 140 àti Àdúrà