Friday
“Jèhófà Ọlọ́run rẹ ni o gbọ́dọ̀ jọ́sìn”—Mátíù 4:10
Àárọ̀
- 9:20 Fídíò Orin 
- 9:30 Orin 74 àti Àdúrà 
- 9:40 Ọ̀RỌ̀ ALÁGA: Kí Ni Ìjọsìn Mímọ́? (Àìsáyà 48:17; Málákì 3:16) 
- 10:10 FÍDÍÒ ÌTÀN BÍBÉLÌ: - Ìhìn Rere Látọ̀dọ̀ Jésù: Abala 2 - “Èyí ni Ọmọ Mi”—Apá Kìíní (Mátíù 3:1–4:11; Máàkù 1:12, 13; Lúùkù 3:1–4:7; Jòhánù 1:7, 8) 
- 10:40 Orin 122 àti Ìfilọ̀ 
- 10:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà Ṣẹ!—Apá Kìíní - • Ọlọ́run Pè É Ní Ọmọ Rẹ̀ (Sáàmù 2:7; Mátíù 3:16, 17; Ìṣe 13:33, 34) 
- • Ìdílé Dáfídì Ló Ti Wá (2 Sámúẹ́lì 7:12, 13; Mátíù 1:1, 2, 6) 
- • Ó Di “Mèsáyà Aṣáájú” (Dáníẹ́lì 9:25; Lúùkù 3:1, 2, 21-23) 
 
- 11:45 Ta Ló Ń Ṣàkóso Ayé Yìí Gan-an? (Máàkù 12:17; Lúùkù 4:5-8; Jòhánù 18:36) 
- 12:15 Orin 22 àti Àkókò Ìsinmi 
Ọ̀sán
- 1:35 Fídíò Orin 
- 1:45 Orin 121 
- 1:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Bí Jésù Ṣe Dá Sátánì Lóhùn! - • Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ni Kó O Gbára Lé (Mátíù 4:1-4) 
- • Má Ṣe Dán Jèhófà Wò (Mátíù 4:5-7) 
- • Jèhófà Nìkan Ni Kó O Jọ́sìn (Mátíù 4:10; Lúùkù 4:5-7) 
- • Fi Ìgboyà Sọ Ohun Tó O Gbà Gbọ́ (1 Pétérù 3:15) 
 
- 2:50 Orin 97 àti Ìfilọ̀ 
- 3:00 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ohun Tá A Kọ́ Nípa Ibi tí Jésù Dé - • Aginjù Jùdíà (Mátíù 3:1-4; Lúùkù 4:1) 
- • Àfonífojì Jọ́dánì (Mátíù 3:13-15; Jòhánù 1:27, 30) 
- • Jerúsálẹ́mù (Mátíù 23:37, 38) 
- • Samáríà (Jòhánù 4:7-9, 40-42) 
- • Gálílì (Mátíù 13:54-57) 
- • Foníṣíà (Lúùkù 4:25, 26) 
- • Síríà (Lúùkù 4:27) 
 
- 4:10 Kí Ni Jésù Ń Rí Lára Rẹ? (Jòhánù 2:25) 
- 4:45 Orin 34 àti Àdúrà Ìparí