Saturday
“Ìtara ilé rẹ máa gbà mí lọ́kàn”—Jòhánù 2:17
Àárọ̀
- 9:20 Fídíò Orin 
- 9:30 Orin 93 àti Àdúrà 
- 9:40 “Kí Lẹ̀ Ń Wá?” (Jòhánù 1:38) 
- 9:50 FÍDÍÒ ÌTÀN BÍBÉLÌ: - Ìhìn Rere Látọ̀dọ̀ Jésù: Abala 2 - “Èyí ni Ọmọ Mi”—Apá Kejì (Jòhánù 1:19–2:25) 
- 10:20 Orin 54 àti Ìfilọ̀ 
- 10:30 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Tó Nífẹ̀ẹ́ Ìjọsìn Mímọ́! - • Jòhánù Arinibọmi (Mátíù 11:7-10) 
- • Áńdérù (Jòhánù 1:35-42) 
- • Pétérù (Lúùkù 5:4-11) 
- • Jòhánù (Mátíù 20:20, 21) 
- • Jémíìsì (Máàkù 3:17) 
- • Fílípì (Jòhánù 1:43) 
- • Nàtáníẹ́lì (Jòhánù 1:45-47) 
 
- 11:35 ÌRÌBỌMI: Àǹfààní Wo Lo Máa Rí Tó O Bá Ṣèrìbọmi? (Málákì 3:17; Ìṣe 19:4; 1 Kọ́ríńtì 10:1, 2) 
- 12:05 Orin 52 àti Àkókò Ìsinmi 
Ọ̀sán
- 1:35 Fídíò Orin 
- 1:45 Orin 36 
- 1:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ohun Tá A Kọ́ Nínú Iṣẹ́ Ìyanu Tí Jésù Kọ́kọ́ Ṣe - • Máa Ṣàánú (Gálátíà 6:10; 1 Jòhánù 3:17) 
- • Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ (Mátíù 6:2-4; 1 Pétérù 5:5) 
- • Jẹ́ Ọ̀làwọ́ (Diutarónómì 15:7, 8; Lúùkù 6:38) 
 
- 2:20 Báwo Ni “Ọ̀dọ́ Àgùntàn Ọlọ́run” Ṣe Kó Ẹ̀ṣẹ̀ Aráyé Lọ? (Jòhánù 1:29; 3:14-16) 
- 2:45 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà Ṣẹ!—Apá Kejì - • Ìtara Ilé Jèhófà Gbà Á Lọ́kàn (Sáàmù 69:9; Jòhánù 2:13-17) 
- • Ó Kéde “Ìhìn Rere fún Àwọn Oníwà Pẹ̀lẹ́” (Àìsáyà 61:1, 2) 
- • Ó Tan “Ìmọ́lẹ̀ Tó Tàn Yòò” ní Gálílì (Àìsáyà 9:1, 2) 
 
- 3:20 Orin 117 àti Ìfilọ̀ 
- 3:30 “Ẹ Kó Àwọn Nǹkan Yìí Kúrò Níbí!” (Jòhánù 2:13-16) 
- 4:00 ‘Màá Kọ́ Ọ’ (Jòhánù 2:18-22) 
- 4:35 Orin 75 àti Àdúrà Ìparí