Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí:
- 1. Tá a bá gba ìhìn rere gbọ́, báwo ni ìyẹn ṣe máa mú kí ìwà wa dáa sí i? (Fílí. 1:27; 3:8) 
- 2. Kí ni ìhìn rere ń mú ká ṣe? (Kól. 1:5, 6) 
- 3. Kí ló ń jẹ́ kó wù wá láti máa wàásù ìhìn rere nìṣó? (2 Pét. 3:11, 12; 1 Kọ́r. 9:19, 23) 
- 4. Báwo la ṣe lè dámọ̀ràn ara wa bí òjíṣẹ́ Ọlọ́run? (2 Kọ́r. 6:4-8) 
- 5. Báwo ni ìhìn rere ṣe ń kọ́ wa? (Títù 2:11-14) 
© 2024 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
CA-copgm25-YR