Ìdílé Jèhófà Tó Wà Níṣọ̀kan
Àárọ̀
- 9:30 Ohùn Orin 
- 9:40 Orin 85 àti Àdúrà 
- 9:50 Mọyì Àǹfààní Tó O Ní Láti Wà Nínú Ìdílé Jèhófà 
- 10:05 Àpínsọ Àsọyé: Wọ́n Mára Tu Àwọn Míì - • Élíhù 
- • Lìdíà 
- • Jésù 
 
- 11:05 Orin 100 àti Ìfilọ̀ 
- 11:15 Máa Ran Àwọn Míì Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Di Ara Ìdílé Jèhófà 
- 11:30 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi 
- 12:00 Orin 135 
Ọ̀sán
- 1:10 Ohùn Orin 
- 1:20 Orin 132 àti Àdúrà 
- 1:30 Àsọyé fún Gbogbo Èèyàn: Ṣé Ayọ̀ àti Àlàáfíà Wà Nínú Ìdílé Rẹ? 
- 2:00 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ 
- 2:30 Orin 136 àti Ìfilọ̀ 
- 2:40 Àpínsọ Àsọyé: Bó O Ṣe Lè Jẹ́ Kí Àlàáfíà Wà - • Máa Sọ “Ọ̀rọ̀ Tó Ń Gbéni Ró” 
- • “Máa Rìn Nínú Ìfẹ́” 
- • Má Ṣe Jẹ́ Káwọn Ọ̀tá Wa Dẹkùn Mú Ẹ 
 
- 3:40 ‘Máa Dúpẹ́ Nígbà Gbogbo’ Nítorí Ìdílé Wa Nípa Tẹ̀mí 
- 4:15 Orin 107 àti Àdúrà