ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 19-25
Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Jẹ́ Ká Mọ Púpọ̀ Sí I Nípa Mèsáyà
| ÌWÉ MÍMỌ́ | ÀSỌTẸ́LẸ̀ | ÌMÚṢẸ ÀSỌTẸ́LẸ̀ | 
|---|---|---|
| Bíi pé Ọlọ́run fi í sílẹ̀ | ||
| Wọ́n kẹ́gàn rẹ̀ lórí òpó igi oró | ||
| Wọ́n kàn-án mọ́gi | ||
| Wọ́n ṣẹ́ kèké lé aṣọ rẹ̀ | ||
| Ó mú ipò iwájú nínú pípolongo orúkọ Jèhófà |