ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÚÙKÙ 23-24
Ṣe Tán Láti Dárí Jini
Ta ni mo gbọ́dọ̀ dárí jì?
Kí ni gbólóhùn náà “ṣe tán láti dárí jini” túmọ̀ sí? (Sm 86:5) Jèhófà àti Ọmọ rẹ̀ máa ń kíyè sí ọkàn ẹni tó bá dẹ́ṣẹ̀ tó sì wá yí pa dà, kí wọ́n lè dárí jì í.
Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.
Má bínú, fídíò yìí kò jáde.