September 8 Ojú ìwé 2 Ṣópin Ti Dé Bá Ìbẹ̀rù Ohun Ìjà Ọ̀gbálẹ̀gbáràwé Ni? Ó Dájú Pé Ewu Ohun Ìjà Ọ̀gbálẹ̀gbáràwé Kò Tíì Kásẹ̀ Nílẹ̀ Ọjọ́ Ọ̀la Aláàbò Níkẹyìn! Kí Ni Ojúṣe Ẹni Rere Nílùú? Sísin Ọlọ́run ní Bèbè Ikú Wọ́n Pinnu Láti Má Ṣe Juwọ́ Sílẹ̀ Ẹ̀pà Lílọ̀—Bí Wọ́n Ṣe Ń ṣe é Ní Áfíríkà Ìsìn Ń Wọ̀ọ̀kùn ní Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì Èmi Kìnnìún Tí Ń Bú Ramúramù Nígbà Kan Rí Wá Di Àgùntàn Onínú Tútù Wíwo Ayé Ǹjẹ́ Ìfàjẹ̀sínilára Tiẹ̀ Pọndandan? “Ìwé Gidi Mà Lèyí O!”