ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 38-44
Jèhófà Máa Ń Gbé Àwọn Aláìsàn Ró
Àwọn olóòótọ́ ìránṣẹ́ Ọlọ́run gbà pé Jèhófà máa ran àwọn lọ́wọ́ nígbà ìṣòro
- Dáfídì ṣàìsàn gan-an 
- Dáfídì gba ti àwọn ẹni rírẹlẹ̀ rò 
- Dáfídì kò retí pé kí Jèhófà wo òun sàn lọ́nà ìyanu, àmọ́ ó bẹ Jèhófà pé kó tu òun nínú, kó fún òun lọ́gbọ́n, kó sì ran òun lọ́wọ́ 
- Jèhófà ka Dáfídì sí ọkùnrin oníwà títọ́