DÁNÍẸ́LÌ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  - 
- Àwọn ará Bábílónì dó ti Jerúsálẹ́mù (1, 2) 
- Wọ́n dìídì dá àwọn ọmọ ọba tí wọ́n kó lẹ́rú lẹ́kọ̀ọ́ (3-5) 
- Wọ́n dán ìṣòtítọ́ àwọn Hébérù mẹ́rin wò (6-21) 
 
-  2  - 
- Ọba Nebukadinésárì lá àlá tó bà á lẹ́rù (1-4) 
- Amòye kankan ò lè rọ́ àlá náà (5-13) 
- Dáníẹ́lì ní kí Ọlọ́run ran òun lọ́wọ́ (14-18) 
- Dáníẹ́lì yin Ọlọ́run torí pé Ó ṣí àṣírí náà payá (19-23) 
- Dáníẹ́lì rọ́ àlá náà fún ọba (24-35) 
- Ìtumọ̀ àlá náà (36-45) 
- Ọba dá Dáníẹ́lì lọ́lá (46-49) 
 
-  3  - 
- Ère wúrà tí Ọba Nebukadinésárì ṣe (1-7) 
- Wọ́n fẹ̀sùn kan àwọn Hébérù mẹ́ta pé wọn ò ṣègbọràn (8-18) 
- Wọ́n jù wọ́n sínú iná ìléru (19-23) 
- Ọlọ́run gbà wọ́n sílẹ̀ nínú iná náà lọ́nà ìyanu (24-27) 
- Ọba gbé Ọlọ́run àwọn Hébérù ga (28-30) 
 
-  4  - 
- Ọba Nebukadinésárì gbà pé Ọlọ́run ni ọba (1-3) 
- Ọba lá àlá nípa igi kan (4-18) 
- Dáníẹ́lì túmọ̀ àlá náà (19-27) 
- Ó kọ́kọ́ ṣẹ sí ọba lára (28-36) 
- Ọba gbé Ọlọ́run ọ̀run ga (37) 
 
-  5  
-  6  - 
- Àwọn ìjòyè ilẹ̀ Páṣíà gbìmọ̀ pọ̀ láti mú Dáníẹ́lì (1-9) 
- Dáníẹ́lì ò yéé gbàdúrà (10-15) 
- Wọ́n ju Dáníẹ́lì sínú ihò kìnnìún (16-24) 
- Ọba Dáríúsì bọlá fún Ọlọ́run Dáníẹ́lì (25-28) 
 
-  7  - 
- Ìran àwọn ẹranko mẹ́rin (1-8) 
- Ẹni Ọjọ́ Àtayébáyé mú ìjókòó ní kọ́ọ̀tù (9-14) 
- A fi ìtumọ̀ han Dáníẹ́lì (15-28) - 
- Ọba mẹ́rin ni àwọn ẹranko mẹ́rin náà (17) 
- Àwọn ẹni mímọ́ máa gba ìjọba (18) 
- Ìwo mẹ́wàá, tàbí ọba mẹ́wàá, máa dìde (24) 
 
 
-  8  
-  9  - 
- Dáníẹ́lì gbàdúrà ìjẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ (1-19) 
- Gébúrẹ́lì wá bá Dáníẹ́lì (20-23) 
- Àsọtẹ́lẹ̀ nípa àádọ́rin ọ̀sẹ̀ (24-27) 
 
- 10  
- 11  
- 12