JÒHÁNÙ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  - 
- Ọ̀rọ̀ náà di ẹlẹ́ran ara (1-18) 
- Jòhánù Arinibọmi jẹ́rìí (19-28) 
- Jésù ni Ọ̀dọ́ Àgùntàn Ọlọ́run (29-34) 
- Àwọn ọmọ ẹ̀yìn tí Jésù kọ́kọ́ yàn (35-42) 
- Fílípì àti Nàtáníẹ́lì (43-51) 
 
-  2  - 
- Ìgbéyàwó ní Kánà; omi di wáìnì (1-12) 
- Jésù fọ tẹ́ńpìlì mọ́ (13-22) 
- Jésù mọ ohun tó wà nínú èèyàn (23-25) 
 
-  3  
-  4  - 
- Jésù àti obìnrin ará Samáríà (1-38) 
- Ọ̀pọ̀ àwọn ará Samáríà gba Jésù gbọ́ (39-42) 
- Jésù wo ọmọkùnrin òṣìṣẹ́ ọba kan sàn (43-54) 
 
-  5  - 
- Ó wo ọkùnrin kan sàn ní Bẹtisátà (1-18) 
- Jésù gba àṣẹ lọ́dọ̀ Baba rẹ̀ (19-24) 
- Àwọn òkú máa gbọ́ ohùn Jésù (25-30) 
- Àwọn ẹ̀rí nípa Jésù (31-47) 
 
-  6  - 
- Jésù bọ́ 5,000 èèyàn (1-15) 
- Jésù rìn lórí omi (16-21) 
- Jésù ni “oúnjẹ ìyè” (22-59) 
- Ọ̀pọ̀ èèyàn kọsẹ̀ nítorí ọ̀rọ̀ Jésù (60-71) 
 
-  7  - 
- Jésù lọ síbi Àjọyọ̀ Àwọn Àgọ́ Ìjọsìn (1-13) 
- Jésù ń kọ́ni níbi àjọyọ̀ náà (14-24) 
- Oríṣiríṣi ohun tí àwọn èèyàn ń sọ nípa Kristi (25-52) 
 
-  8  - 
- Baba ń jẹ́rìí nípa Jésù (12-30) 
- Àwọn ọmọ Ábúráhámù (31-41) 
- Àwọn ọmọ Èṣù (42-47) 
- Jésù àti Ábúráhámù (48-59) 
 
-  9  - 
- Jésù wo ọkùnrin tí wọ́n bí ní afọ́jú sàn (1-12) 
- Àwọn Farisí ń bi ọkùnrin tó wò sàn ní ìbéèrè (13-34) 
- Àwọn Farisí fọ́jú (35-41) 
 
- 10  - 
- Olùṣọ́ àgùntàn àti ọgbà àgùntàn (1-21) 
- Àwọn Júù ta ko Jésù níbi Àjọyọ̀ Ìyàsímímọ́ (22-39) - 
- Ọ̀pọ̀ àwọn Júù ò gbà gbọ́ (24-26) 
- “Àwọn àgùntàn mi máa ń fetí sí ohùn mi” (27) 
- Ọmọ wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Baba (30, 38) 
 
- Ọ̀pọ̀ àwọn tó wà ní òdìkejì Jọ́dánì gbà gbọ́ (40-42) 
 
- 11  - 
- Ikú Lásárù (1-16) 
- Jésù tu Màtá àti Màríà nínú (17-37) 
- Jésù jí Lásárù dìde (38-44) 
- Wọ́n gbìmọ̀ láti pa Jésù (45-57) 
 
- 12  - 
- Màríà da òróró sí ẹsẹ̀ Jésù (1-11) 
- Jésù gun ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ wọnú ìlú (12-19) 
- Jésù sọ tẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀ (20-37) 
- Àìnígbàgbọ́ àwọn Júù mú àsọtẹ́lẹ̀ ṣẹ (38-43) 
- Jésù wá gba ayé là (44-50) 
 
- 13  - 
- Jésù fọ ẹsẹ̀ àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ (1-20) 
- Jésù fi hàn pé Júdásì ló máa da òun (21-30) 
- Àṣẹ tuntun (31-35) 
- Ó sọ tẹ́lẹ̀ pé Pétérù máa sẹ́ òun (36-38) 
 
- 14  
- 15  - 
- Àpèjúwe àjàrà tòótọ́ (1-10) 
- Kristi pàṣẹ pé kí wọ́n ní irú ìfẹ́ tí òun ní (11-17) 
- Ayé kórìíra àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jésù (18-27) 
 
- 16  - 
- Wọ́n lè pa àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jésù (1-4a) 
- Iṣẹ́ tí ẹ̀mí mímọ́ máa ṣe (4b-16) 
- Ìbànújẹ́ àwọn ọmọ ẹ̀yìn máa di ayọ̀ (17-24) 
- Jésù ti ṣẹ́gun ayé (25-33) 
 
- 17  
- 18  - 
- Júdásì da Jésù (1-9) 
- Pétérù lo idà (10, 11) 
- Wọ́n mú Jésù lọ sọ́dọ̀ Ánásì (12-14) 
- Ìgbà àkọ́kọ́ tí Pétérù sẹ́ (15-18) 
- Jésù dé iwájú Ánásì (19-24) 
- Pétérù sẹ́ lẹ́ẹ̀kejì àti lẹ́ẹ̀kẹta (25-27) 
- Jésù dé iwájú Pílátù (28-40) 
 
- 19  - 
- Wọ́n na Jésù, wọ́n sì fi ṣe yẹ̀yẹ́ (1-7) 
- Pílátù tún bi Jésù léèrè ọ̀rọ̀ (8-16a) 
- Wọ́n kan Jésù mọ́ òpó igi ní Gọ́gọ́tà (16b-24) 
- Jésù ṣètò bí wọ́n ṣe máa bójú tó ìyá rẹ̀ (25-27) 
- Ikú Jésù (28-37) 
- Wọ́n sìnkú Jésù (38-42) 
 
- 20  - 
- Ibojì ṣófo (1-10) 
- Jésù fara han Màríà Magidalénì (11-18) 
-  Jésù fara han àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ (19-23) 
- Tọ́másì ṣiyèméjì, àmọ́ ó pa dà dá a lójú (24-29) 
- Ìdí tí wọ́n fi kọ àkájọ ìwé yìí (30, 31) 
 
- 21  - 
- Jésù fara han àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ (1-14) 
- Pétérù fi dá Jésù lójú pé òun nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ (15-19) 
- Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí ọmọ ẹ̀yìn tí Jésù nífẹ̀ẹ́ (20-23) 
- Ọ̀rọ̀ ìparí (24, 25)