ÉFÉSÙ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  - 
- Ìkíni (1, 2) 
- Àwọn ìbùkún tẹ̀mí (3-7) 
- À ń kó ohun gbogbo jọ nínú Kristi (8-14) - 
- “Iṣẹ́ àbójútó kan” ní àwọn àkókò tí a ti yàn (10) 
- A fi ẹ̀mí gbé èdìdì lé wọn gẹ́gẹ́ bí “àmì ìdánilójú” (13, 14) 
 
- Pọ́ọ̀lù dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run nítorí ìgbàgbọ́ àwọn ará Éfésù, ó sì gbàdúrà fún wọn (15-23) 
 
-  2  
-  3  
-  4  
-  5  - 
- Ọ̀rọ̀ mímọ́ àti ìwà mímọ́ (1-5) 
- Ẹ máa rìn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ìmọ́lẹ̀ (6-14) 
- Ẹ máa kún fún ẹ̀mí (15-20) 
- Ìmọ̀ràn fún àwọn ọkọ àti ìyàwó (21-33) 
 
-  6  - 
- Ìmọ̀ràn fún àwọn ọmọ àti òbí (1-4) 
- Ìmọ̀ràn fún àwọn ẹrú àti ọ̀gá (5-9) 
- Gbogbo ìhámọ́ra ogun láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run (10-20) 
- Ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (21-24)