ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • scl ojú ìwé 85
  • Ìwà Àìlọ́wọ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìwà Àìlọ́wọ̀
  • Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tó Lè Ran Àwa Kristẹni Lọ́wọ́
Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tó Lè Ran Àwa Kristẹni Lọ́wọ́
scl ojú ìwé 85

Ìwà Àìlọ́wọ̀

Irú àwọn ìwà tí kò fọ̀wọ̀ hàn wo ló yẹ ká yẹra fún?

Sm 10:13; 3Jo 9, 10

Tún wo Sm 74:10, 18; Jud 8, 10

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • 1Sa 2:12-17, 22-25, 27-30—Àwọn ọmọ Élì Àlùfáà Àgbà kò bọ̀wọ̀ fún ìjọsìn Jèhófà, àmọ́ Élì kò bá wọn wí, èyí sì fi hàn pé kò bọ̀wọ̀ fún Jèhófà

    • 2Ọb 1:9-15—Jèhófà pa àwọn ọmọ ogun tí kò bọ̀wọ̀ fún wòlíì Èlíjà, àmọ́ ó ṣàánú àwọn ọmọ ogun tó nírẹ̀lẹ̀

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́