Jẹ́nẹ́sísì 35:18, 19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Bí ẹ̀mí rẹ̀ ṣe ń bọ́ lọ* (torí ó ń kú lọ), ó sọ ọmọ náà ní Bẹni-ónì,* àmọ́ bàbá rẹ̀ sọ ọ́ ní Bẹ́ńjámínì.*+ 19 Réṣẹ́lì wá kú, wọ́n sì sin ín ní ojú ọ̀nà Éfúrátì, ìyẹn Bẹ́tílẹ́hẹ́mù.+ Jẹ́nẹ́sísì 42:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àmọ́ Jékọ́bù ò jẹ́ kí Bẹ́ńjámínì+ àbúrò Jósẹ́fù tẹ̀ lé àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ yòókù, torí ó sọ pé: “Jàǹbá lè lọ ṣe é.”+
18 Bí ẹ̀mí rẹ̀ ṣe ń bọ́ lọ* (torí ó ń kú lọ), ó sọ ọmọ náà ní Bẹni-ónì,* àmọ́ bàbá rẹ̀ sọ ọ́ ní Bẹ́ńjámínì.*+ 19 Réṣẹ́lì wá kú, wọ́n sì sin ín ní ojú ọ̀nà Éfúrátì, ìyẹn Bẹ́tílẹ́hẹ́mù.+
4 Àmọ́ Jékọ́bù ò jẹ́ kí Bẹ́ńjámínì+ àbúrò Jósẹ́fù tẹ̀ lé àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ yòókù, torí ó sọ pé: “Jàǹbá lè lọ ṣe é.”+