ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 46:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì+ ni Bélà, Békérì, Áṣíbélì, Gérà,+ Náámánì, Éhì, Róṣì, Múpímù, Húpímù+ àti Áádì.+

  • Jẹ́nẹ́sísì 49:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 “Bẹ́ńjámínì+ yóò máa fani ya bí ìkookò.+ Ní àárọ̀, yóò jẹ ẹran tó pa. Ní ìrọ̀lẹ́, yóò pín ẹrù ogun.”+

  • Diutarónómì 33:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  12 Ó sọ nípa Bẹ́ńjámínì pé:+

      “Kí ẹni ọ̀wọ́n Jèhófà máa gbé láìséwu lọ́dọ̀ rẹ̀;

      Bó ṣe ń dáàbò bò ó ní gbogbo ọjọ́,

      Á máa gbé láàárín èjìká rẹ̀.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́