Jẹ́nẹ́sísì 28:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wò ó! Jèhófà wà lókè rẹ̀, ó sì sọ pé: “Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run Ábúráhámù bàbá rẹ àti Ọlọ́run Ísákì.+ Ìwọ àti àtọmọdọ́mọ*+ rẹ ni màá fún ní ilẹ̀ tí o dùbúlẹ̀ sí yìí. Jẹ́nẹ́sísì 28:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ó wá pe orúkọ ibẹ̀ ní Bẹ́tẹ́lì,* àmọ́ Lúsì+ ni ìlú náà ń jẹ́ tẹ́lẹ̀. Hósíà 12:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ó bá áńgẹ́lì kan jà títí ó fi borí. Ó sunkún, ó sì bẹ̀ ẹ́ pé kó ṣojúure sí òun.”+ Ọlọ́run rí i ní Bẹ́tẹ́lì, ibẹ̀ ni Ó sì ti bá wa sọ̀rọ̀,+
13 Wò ó! Jèhófà wà lókè rẹ̀, ó sì sọ pé: “Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run Ábúráhámù bàbá rẹ àti Ọlọ́run Ísákì.+ Ìwọ àti àtọmọdọ́mọ*+ rẹ ni màá fún ní ilẹ̀ tí o dùbúlẹ̀ sí yìí.
4 Ó bá áńgẹ́lì kan jà títí ó fi borí. Ó sunkún, ó sì bẹ̀ ẹ́ pé kó ṣojúure sí òun.”+ Ọlọ́run rí i ní Bẹ́tẹ́lì, ibẹ̀ ni Ó sì ti bá wa sọ̀rọ̀,+