Jẹ́nẹ́sísì 46:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àwọn ọmọ Sébúlúnì+ ni Sérédì, Élónì àti Jálíẹ́lì.+ Jẹ́nẹ́sísì 49:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “Sébúlúnì+ yóò máa gbé ní etíkun, ní èbúté tí àwọn ọkọ̀ òkun gúnlẹ̀ sí,+ ààlà rẹ̀ tó jìnnà jù yóò sì wà ní ọ̀nà Sídónì.+ Diutarónómì 33:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ó sọ nípa Sébúlúnì pé:+ “Ìwọ Sébúlúnì, máa yọ̀ bí o ṣe ń jáde lọ,Àti ìwọ Ísákà, nínú àwọn àgọ́ rẹ.+
13 “Sébúlúnì+ yóò máa gbé ní etíkun, ní èbúté tí àwọn ọkọ̀ òkun gúnlẹ̀ sí,+ ààlà rẹ̀ tó jìnnà jù yóò sì wà ní ọ̀nà Sídónì.+
18 Ó sọ nípa Sébúlúnì pé:+ “Ìwọ Sébúlúnì, máa yọ̀ bí o ṣe ń jáde lọ,Àti ìwọ Ísákà, nínú àwọn àgọ́ rẹ.+