Jẹ́nẹ́sísì 10:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ààlà àwọn ọmọ Kénáánì bẹ̀rẹ̀ láti Sídónì títí lọ dé Gérárì,+ nítòsí Gásà,+ títí lọ dé Sódómù, Gòmórà,+ Ádímà àti Sébóíímù,+ nítòsí Láṣà. Jẹ́nẹ́sísì 12:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ábúrámù rin ilẹ̀ náà já títí dé ibi tí Ṣékémù+ wà, nítòsí àwọn igi ńlá tó wà ní Mórè.+ Àwọn ọmọ Kénáánì wà ní ilẹ̀ náà nígbà yẹn.
19 Ààlà àwọn ọmọ Kénáánì bẹ̀rẹ̀ láti Sídónì títí lọ dé Gérárì,+ nítòsí Gásà,+ títí lọ dé Sódómù, Gòmórà,+ Ádímà àti Sébóíímù,+ nítòsí Láṣà.
6 Ábúrámù rin ilẹ̀ náà já títí dé ibi tí Ṣékémù+ wà, nítòsí àwọn igi ńlá tó wà ní Mórè.+ Àwọn ọmọ Kénáánì wà ní ilẹ̀ náà nígbà yẹn.