ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 15:13, 14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ó wá sọ fún Ábúrámù pé: “Mọ̀ dájú pé àwọn ọmọ* rẹ máa di àjèjì ní ilẹ̀ tí kì í ṣe tiwọn, àwọn èèyàn ibẹ̀ á fi wọ́n ṣe ẹrú, wọ́n á sì fìyà jẹ wọ́n fún ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) ọdún.+ 14 Àmọ́ màá dá orílẹ̀-èdè tí wọn yóò sìn+ lẹ́jọ́, lẹ́yìn náà, wọ́n á kó ọ̀pọ̀ ẹrù+ jáde.

  • Ẹ́kísódù 6:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Èmi fúnra mi ti gbọ́ bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe ń kérora, àwọn tí àwọn ará Íjíbítì fi ń ṣẹrú, mo sì rántí májẹ̀mú mi.+

  • Nọ́ńbà 20:15, 16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Àwọn bàbá wa lọ sí Íjíbítì,+ ọ̀pọ̀ ọdún*+ la sì fi gbé ní Íjíbítì, àwọn ará Íjíbítì sì fìyà jẹ àwa àti àwọn bàbá wa.+ 16 Nígbẹ̀yìn-gbẹ́yín, a ké pe Jèhófà,+ ó gbọ́ wa, ó sì rán áńgẹ́lì+ kan láti mú wa kúrò ní Íjíbítì, a ti wá dé Kádéṣì báyìí, ìlú tó wà ní ààlà ilẹ̀ rẹ.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́