- 
	                        
            
            Jẹ́nẹ́sísì 32:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        9 Lẹ́yìn náà, Jékọ́bù sọ pé: “Ọlọ́run Ábúráhámù bàbá mi àti Ọlọ́run Ísákì bàbá mi, Jèhófà, ìwọ tí ò ń sọ fún mi pé, ‘Pa dà sí ilẹ̀ rẹ àti sọ́dọ̀ àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ, màá sì ṣe dáadáa sí ọ,’+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Ìṣe 7:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        32 ‘Èmi ni Ọlọ́run àwọn baba ńlá rẹ, Ọlọ́run Ábúráhámù àti ti Ísákì àti ti Jékọ́bù.’+ Mósè bẹ̀rẹ̀ sí í gbọ̀n, kò sì gbójúgbóyà láti sọ pé òun fẹ́ wádìí sí i. 
 
-