Ẹ́kísódù 16:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Gbàrà tí Áárónì bá gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sọ̀rọ̀ tán, wọ́n yíjú pa dà, wọ́n sì dojú kọ aginjù. Wò ó! ògo Jèhófà fara hàn nínú ìkùukùu.*+ Léfítíkù 9:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Níkẹyìn, Mósè àti Áárónì lọ sínú àgọ́ ìpàdé, wọ́n jáde wá, wọ́n sì súre fún àwọn èèyàn náà.+ Jèhófà wá fi ògo rẹ̀ han gbogbo àwọn èèyàn náà,+ Nọ́ńbà 16:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Nígbà tí àwọn èèyàn náà kóra jọ, tí wọ́n ń sọ̀rọ̀ sí Mósè àti Áárónì, wọ́n wá yíjú sí àgọ́ ìpàdé, wò ó! ìkùukùu* bo àgọ́ náà, ògo Jèhófà sì bẹ̀rẹ̀ sí í fara hàn.+
10 Gbàrà tí Áárónì bá gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sọ̀rọ̀ tán, wọ́n yíjú pa dà, wọ́n sì dojú kọ aginjù. Wò ó! ògo Jèhófà fara hàn nínú ìkùukùu.*+
23 Níkẹyìn, Mósè àti Áárónì lọ sínú àgọ́ ìpàdé, wọ́n jáde wá, wọ́n sì súre fún àwọn èèyàn náà.+ Jèhófà wá fi ògo rẹ̀ han gbogbo àwọn èèyàn náà,+
42 Nígbà tí àwọn èèyàn náà kóra jọ, tí wọ́n ń sọ̀rọ̀ sí Mósè àti Áárónì, wọ́n wá yíjú sí àgọ́ ìpàdé, wò ó! ìkùukùu* bo àgọ́ náà, ògo Jèhófà sì bẹ̀rẹ̀ sí í fara hàn.+