Ẹ́kísódù 30:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Kí o wá fi ṣe òróró àfiyanni mímọ́; kí o ro àwọn èròjà náà pọ̀ dáadáa.*+ Òróró àfiyanni mímọ́ ni yóò jẹ́. Ẹ́kísódù 30:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Kí o fi ṣe tùràrí;+ kí o ro àwọn èròjà náà pọ̀ dáadáa,* fi iyọ̀ sí i,+ kó jẹ́ ògidì, kó sì jẹ́ mímọ́. Ẹ́kísódù 37:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ó tún ṣe òróró àfiyanni mímọ́+ àti ògidì tùràrí onílọ́fínńdà,+ ó ro àwọn èròjà rẹ̀ pọ̀ dáadáa.*
25 Kí o wá fi ṣe òróró àfiyanni mímọ́; kí o ro àwọn èròjà náà pọ̀ dáadáa.*+ Òróró àfiyanni mímọ́ ni yóò jẹ́.
35 Kí o fi ṣe tùràrí;+ kí o ro àwọn èròjà náà pọ̀ dáadáa,* fi iyọ̀ sí i,+ kó jẹ́ ògidì, kó sì jẹ́ mímọ́.