Ẹ́kísódù 21:23-25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Àmọ́ tó bá la ẹ̀mí lọ, kí o fi ẹ̀mí dípò ẹ̀mí,*+ 24 ojú dípò ojú, eyín dípò eyín, ọwọ́ dípò ọwọ́, ẹsẹ̀ dípò ẹsẹ̀,+ 25 kí o fi nǹkan jó ẹni tó bá fi nǹkan jó ẹnì kejì, ọgbẹ́ dípò ọgbẹ́, ẹ̀ṣẹ́ dípò ẹ̀ṣẹ́. Léfítíkù 24:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Kí ẹ kán eegun ẹni tó bá kán eegun ẹlòmíì, ojú dípò ojú, eyín dípò eyín, ohun tó bá ṣe fún ẹlòmíì ni kí ẹ ṣe fún òun náà.+ Mátíù 5:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 “Ẹ gbọ́ pé a sọ pé: ‘Ojú dípò ojú àti eyín dípò eyín.’+
23 Àmọ́ tó bá la ẹ̀mí lọ, kí o fi ẹ̀mí dípò ẹ̀mí,*+ 24 ojú dípò ojú, eyín dípò eyín, ọwọ́ dípò ọwọ́, ẹsẹ̀ dípò ẹsẹ̀,+ 25 kí o fi nǹkan jó ẹni tó bá fi nǹkan jó ẹnì kejì, ọgbẹ́ dípò ọgbẹ́, ẹ̀ṣẹ́ dípò ẹ̀ṣẹ́.
20 Kí ẹ kán eegun ẹni tó bá kán eegun ẹlòmíì, ojú dípò ojú, eyín dípò eyín, ohun tó bá ṣe fún ẹlòmíì ni kí ẹ ṣe fún òun náà.+