Léfítíkù 26:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Mi ò ní fojúure wò yín, àwọn ọ̀tá yín á sì ṣẹ́gun yín;+ àwọn tó kórìíra yín yóò tẹ̀ yín mọ́lẹ̀,+ ẹ ó sì sá nígbà tí ẹnì kankan ò lé yín.+ Àìsáyà 30:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ẹgbẹ̀rún kan (1,000) máa gbọ̀n rìrì nítorí ìhàlẹ̀ ẹnì kan;+Ìhàlẹ̀ ẹni márùn-ún máa mú kí ẹ sá,Títí ohun tó ṣẹ́ kù nínú yín fi máa dà bí òpó lórí òkè ńlá,Bí òpó tí wọ́n fi ṣe àmì lórí òkè kékeré.+
17 Mi ò ní fojúure wò yín, àwọn ọ̀tá yín á sì ṣẹ́gun yín;+ àwọn tó kórìíra yín yóò tẹ̀ yín mọ́lẹ̀,+ ẹ ó sì sá nígbà tí ẹnì kankan ò lé yín.+
17 Ẹgbẹ̀rún kan (1,000) máa gbọ̀n rìrì nítorí ìhàlẹ̀ ẹnì kan;+Ìhàlẹ̀ ẹni márùn-ún máa mú kí ẹ sá,Títí ohun tó ṣẹ́ kù nínú yín fi máa dà bí òpó lórí òkè ńlá,Bí òpó tí wọ́n fi ṣe àmì lórí òkè kékeré.+