Léfítíkù 26:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 “‘Ní ti àwọn tó bá yè é,+ màá fi ìbẹ̀rù kún ọkàn wọn ní ilẹ̀ àwọn ọ̀tá wọn; ìró ewé tí atẹ́gùn ń fẹ́ máa lé wọn sá, wọ́n á fẹsẹ̀ fẹ bí ẹni ń sá fún idà, wọ́n á sì ṣubú láìsí ẹni tó ń lé wọn.+ Diutarónómì 32:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Báwo ni ẹnì kan ṣe lè lé ẹgbẹ̀rún kan (1,000),Kí ẹni méjì sì mú kí ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) sá?+ Tí kì í bá ṣe pé Àpáta wọn ti tà wọ́n,+Tí Jèhófà sì ti fi wọ́n lé ọ̀tá lọ́wọ́.
36 “‘Ní ti àwọn tó bá yè é,+ màá fi ìbẹ̀rù kún ọkàn wọn ní ilẹ̀ àwọn ọ̀tá wọn; ìró ewé tí atẹ́gùn ń fẹ́ máa lé wọn sá, wọ́n á fẹsẹ̀ fẹ bí ẹni ń sá fún idà, wọ́n á sì ṣubú láìsí ẹni tó ń lé wọn.+
30 Báwo ni ẹnì kan ṣe lè lé ẹgbẹ̀rún kan (1,000),Kí ẹni méjì sì mú kí ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) sá?+ Tí kì í bá ṣe pé Àpáta wọn ti tà wọ́n,+Tí Jèhófà sì ti fi wọ́n lé ọ̀tá lọ́wọ́.