21 Tí ẹnì kan bá fara kan ohunkóhun tó jẹ́ aláìmọ́, yálà ohun àìmọ́ ti èèyàn+ tàbí ẹranko aláìmọ́+ tàbí ohunkóhun tó jẹ́ aláìmọ́ tó sì ń ríni lára,+ tí ẹni náà sì jẹ lára ẹran ẹbọ ìrẹ́pọ̀ náà, tó jẹ́ ti Jèhófà, kí ẹ pa ẹni náà, kí ẹ lè mú un kúrò láàárín àwọn èèyàn rẹ̀.’”