-
Ẹ́kísódù 25:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Màá pàdé rẹ níbẹ̀, màá sì bá ọ sọ̀rọ̀ látorí ìbòrí náà.+ Láti àárín àwọn kérúbù méjì tó wà lórí àpótí Ẹ̀rí náà ni màá ti jẹ́ kí o mọ gbogbo ohun tí màá pa láṣẹ fún ọ pé kí o sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.
-
-
Ẹ́kísódù 30:36Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
36 Kí o gún lára rẹ̀, kó sì kúnná, kí o wá bù lára rẹ̀ síwájú Ẹ̀rí nínú àgọ́ ìpàdé, níbi tí màá ti pàdé rẹ. Kó jẹ́ mímọ́ jù lọ fún yín.
-