ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 7:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Kálukú wọn ju ọ̀pá rẹ̀ sílẹ̀, àwọn ọ̀pá náà sì di ejò ńlá; àmọ́ ọ̀pá Áárónì gbé àwọn ọ̀pá wọn mì.

  • Ẹ́kísódù 7:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Sọ fún Áárónì pé, ‘Mú ọ̀pá rẹ, kí o sì na ọwọ́ rẹ sórí omi Íjíbítì,+ sórí àwọn odò rẹ̀, àwọn omi tó ń ṣàn láti ibẹ̀,* àwọn irà rẹ̀+ àti gbogbo adágún omi rẹ̀, kí wọ́n lè di ẹ̀jẹ̀.’ Ẹ̀jẹ̀ yóò wà ní gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì, títí kan inú àwọn ọpọ́n onígi àtèyí tí wọ́n fi òkúta ṣe.”

  • Nọ́ńbà 17:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Dá ọ̀pá+ Áárónì pa dà síwájú Ẹ̀rí, kó máa wà níbẹ̀, kó lè jẹ́ àmì+ fún àwọn ọmọ ọlọ̀tẹ̀,+ kí wọ́n má bàa kùn sí mi mọ́, kí wọ́n má bàa kú.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́