Léfítíkù 19:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “‘Kí kálukú yín máa bọ̀wọ̀ fún* ìyá rẹ̀ àti bàbá rẹ̀,+ kí ẹ sì máa pa àwọn sábáàtì+ mi mọ́. Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín. Òwe 31:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Tó bá la ẹnu rẹ̀, ọ̀rọ̀ ọgbọ́n ló ń jáde,+Òfin inú rere* sì wà ní ahọ́n rẹ̀. 2 Tímótì 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Torí mo rántí ìgbàgbọ́ rẹ tí kò ní ẹ̀tàn,+ èyí tí ìyá rẹ àgbà Lọ́ìsì àti ìyá rẹ Yùníìsì kọ́kọ́ ní, ó sì dá mi lójú pé irú ìgbàgbọ́ yìí ni ìwọ náà ní.
3 “‘Kí kálukú yín máa bọ̀wọ̀ fún* ìyá rẹ̀ àti bàbá rẹ̀,+ kí ẹ sì máa pa àwọn sábáàtì+ mi mọ́. Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.
5 Torí mo rántí ìgbàgbọ́ rẹ tí kò ní ẹ̀tàn,+ èyí tí ìyá rẹ àgbà Lọ́ìsì àti ìyá rẹ Yùníìsì kọ́kọ́ ní, ó sì dá mi lójú pé irú ìgbàgbọ́ yìí ni ìwọ náà ní.