9 Àmọ́ ẹ má ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà, ẹ má sì bẹ̀rù àwọn èèyàn ilẹ̀ náà,+ torí a máa jẹ wọ́n run.* Ààbò wọn ti kúrò lórí wọn, Jèhófà sì wà pẹ̀lú wa.+ Ẹ má bẹ̀rù wọn.”
24 Torí náà, àwọn ọmọ wọn wọlé, wọ́n sì gba ilẹ̀ náà,+ o ṣẹ́gun àwọn ọmọ Kénáánì tó ń gbé ilẹ̀ náà níwájú wọn,+ o sì fi wọ́n lé wọn lọ́wọ́, látorí àwọn ọba wọn dórí àwọn èèyàn ilẹ̀ náà, kí wọ́n lè ṣe wọ́n bí wọ́n ṣe fẹ́.