1 Àwọn Ọba 5:15, 16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Sólómọ́nì ní ọ̀kẹ́ mẹ́ta ààbọ̀ (70,000) lébìrà* àti ọ̀kẹ́ mẹ́rin (80,000) àwọn tó ń gé òkúta+ ní àwọn òkè+ 16 àti ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (3,300) ìjòyè+ tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ àbójútó láti máa darí àwọn òṣìṣẹ́.
15 Sólómọ́nì ní ọ̀kẹ́ mẹ́ta ààbọ̀ (70,000) lébìrà* àti ọ̀kẹ́ mẹ́rin (80,000) àwọn tó ń gé òkúta+ ní àwọn òkè+ 16 àti ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (3,300) ìjòyè+ tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ àbójútó láti máa darí àwọn òṣìṣẹ́.