ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 16:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Níkẹyìn, Jèhófà sọ fún Sámúẹ́lì pé: “Ìgbà wo lo máa ṣọ̀fọ̀ Sọ́ọ̀lù dà,+ ní báyìí tí mo ti kọ Sọ́ọ̀lù pé kí ó má ṣe jẹ́ ọba lórí Ísírẹ́lì mọ́?+ Rọ òróró sínú ìwo,+ kí o sì lọ. Màá rán ọ lọ sọ́dọ̀ Jésè+ ará Bẹ́tílẹ́hẹ́mù, nítorí mo ti yan ọ̀kan lára àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ láti jẹ́ ọba fún mi.”+

  • 1 Àwọn Ọba 1:39
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 39 Ni àlùfáà Sádókù bá mú ìwo òróró+ láti inú àgọ́,+ ó sì fòróró yan Sólómọ́nì,+ wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ sí í fun ìwo, gbogbo èèyàn náà sì ń kígbe pé: “Kí ẹ̀mí Ọba Sólómọ́nì gùn o!”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́