Òwe 29:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ẹni tó ń mú ọrùn rẹ̀ le* lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìbáwí +Yóò pa run lójijì láìsí àtúnṣe.+ Òwe 30:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ojú tó ń fi bàbá ṣẹ̀sín, tí kì í sì í ṣègbọràn sí ìyá,+Àwọn ẹyẹ ìwò tó wà ní àfonífojì yóò yọ ọ́ jáde,Àwọn ọmọ ẹyẹ idì yóò sì mú un jẹ.+
17 Ojú tó ń fi bàbá ṣẹ̀sín, tí kì í sì í ṣègbọràn sí ìyá,+Àwọn ẹyẹ ìwò tó wà ní àfonífojì yóò yọ ọ́ jáde,Àwọn ọmọ ẹyẹ idì yóò sì mú un jẹ.+