-
1 Sámúẹ́lì 14:50Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
50 Orúkọ ìyàwó rẹ̀ ni Áhínóámù ọmọ Áhímáásì. Orúkọ olórí àwọn ọmọ ogun rẹ̀ ni Ábínérì+ ọmọ Nérì tó jẹ́ arákùnrin bàbá Sọ́ọ̀lù.
-
-
1 Sámúẹ́lì 26:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Lẹ́yìn náà, Dáfídì lọ sí ibi tí Sọ́ọ̀lù pàgọ́ sí, Dáfídì sì rí ibi tí Sọ́ọ̀lù àti Ábínérì+ ọmọ Nérì olórí ọmọ ogun rẹ̀ sùn sí; Sọ́ọ̀lù sùn sílẹ̀ ní gbàgede ibùdó pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun tó dó yí i ká.
-