ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 6:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Àmọ́ gbogbo fàdákà, wúrà, àwọn ohun tí wọ́n fi bàbà àti irin ṣe jẹ́ ohun mímọ́ fún Jèhófà.+ Ibi ìṣúra Jèhófà ni kí ẹ kó o lọ.”+

  • 1 Àwọn Ọba 7:51
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 51 Torí náà, Ọba Sólómọ́nì parí gbogbo iṣẹ́ ilé Jèhófà tó yẹ ní ṣíṣe. Lẹ́yìn náà, Sólómọ́nì kó àwọn ohun tí Dáfídì bàbá rẹ̀ ti yà sí mímọ́+ wọlé, ó kó fàdákà, wúrà àti àwọn ohun èlò wá sínú ibi tí wọ́n ń kó ìṣúra sí ní ilé Jèhófà.+

  • 1 Kíróníkà 22:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Wò ó, mo ti sapá gan-an láti pèsè ọ̀kẹ́ márùn-ún (100,000) tálẹ́ńtì* wúrà sílẹ̀ fún ilé Jèhófà àti mílíọ̀nù kan (1,000,000) tálẹ́ńtì fàdákà pẹ̀lú bàbà àti irin+ tó pọ̀ gan-an débi pé kò ṣeé wọ̀n, mo sì ti pèsè àwọn ẹ̀là gẹdú àti òkúta+ sílẹ̀, àmọ́ wàá fi kún wọn.

  • 1 Kíróníkà 26:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Lára àwọn ẹrù + tí wọ́n kó lójú ogun,+ wọ́n ya àwọn ohun kan sí mímọ́ láti máa fi tọ́jú ilé Jèhófà;

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́