2 Sámúẹ́lì 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Sọ́ọ̀lù ní wáhàrì* kan tó ń jẹ́ Rísípà,+ ọmọ Áyà. Lẹ́yìn náà, Íṣí-bóṣétì + sọ fún Ábínérì pé: “Kí ló dé tí o fi bá wáhàrì bàbá mi lò pọ̀?”+ 1 Àwọn Ọba 2:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ni Ọba Sólómọ́nì bá dá ìyá rẹ̀ lóhùn pé: “Kí ló dé tí o fi ní kí n fún Ádóníjà ní Ábíṣágì ará Ṣúnémù? Ò bá kúkú ní kí n fún un ní ìjọba pẹ̀lú+ nítorí pé ẹ̀gbọ́n mi ni,+ ẹ̀yìn rẹ̀ sì ni àlùfáà Ábíátárì àti Jóábù+ ọmọ Seruáyà+ wà.”
7 Sọ́ọ̀lù ní wáhàrì* kan tó ń jẹ́ Rísípà,+ ọmọ Áyà. Lẹ́yìn náà, Íṣí-bóṣétì + sọ fún Ábínérì pé: “Kí ló dé tí o fi bá wáhàrì bàbá mi lò pọ̀?”+
22 Ni Ọba Sólómọ́nì bá dá ìyá rẹ̀ lóhùn pé: “Kí ló dé tí o fi ní kí n fún Ádóníjà ní Ábíṣágì ará Ṣúnémù? Ò bá kúkú ní kí n fún un ní ìjọba pẹ̀lú+ nítorí pé ẹ̀gbọ́n mi ni,+ ẹ̀yìn rẹ̀ sì ni àlùfáà Ábíátárì àti Jóábù+ ọmọ Seruáyà+ wà.”