ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 12:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Wò ó, idà kò ní kúrò ní ilé rẹ láé,+ nítorí pé o kọ̀ mí, tí o sì sọ ìyàwó Ùráyà ọmọ Hétì di tìrẹ.’

  • Òwe 2:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Ní ti àwọn ẹni burúkú, a ó pa wọ́n run kúrò ní ayé,+

      Ní ti àwọn oníbékebèke, a ó fà wọ́n tu kúrò nínú rẹ̀.+

  • Òwe 20:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ẹni tó bá bú bàbá àti ìyá rẹ̀,

      Fìtílà rẹ̀ yóò kú nígbà tí òkùnkùn bá ṣú.+

  • Òwe 30:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ojú tó ń fi bàbá ṣẹ̀sín, tí kì í sì í ṣègbọràn sí ìyá,+

      Àwọn ẹyẹ ìwò tó wà ní àfonífojì yóò yọ ọ́ jáde,

      Àwọn ọmọ ẹyẹ idì yóò sì mú un jẹ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́