-
1 Sámúẹ́lì 14:50Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
50 Orúkọ ìyàwó rẹ̀ ni Áhínóámù ọmọ Áhímáásì. Orúkọ olórí àwọn ọmọ ogun rẹ̀ ni Ábínérì+ ọmọ Nérì tó jẹ́ arákùnrin bàbá Sọ́ọ̀lù.
-
-
2 Sámúẹ́lì 2:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Ábínérì bá sọ fún Ásáhélì lẹ́ẹ̀kan sí i pé: “Dẹ̀yìn lẹ́yìn mi. Ṣé o fẹ́ kí n pa ọ́ ni? Kò yẹ kí n gbójú sókè wo Jóábù ẹ̀gbọ́n rẹ o.”
-