ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 3:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Torí náà, ó lé ọkùnrin náà jáde, ó sì fi àwọn kérúbù+ àti idà oníná tó ń yí láìdáwọ́ dúró sí ìlà oòrùn ọgbà Édẹ́nì, kí wọ́n lè máa ṣọ́ ọ̀nà tó lọ síbi igi ìyè náà.

  • Ẹ́kísódù 25:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Kí o fi wúrà ṣe kérúbù méjì; kó jẹ́ iṣẹ́ ọnà tí o fi òòlù ṣe sí ìkángun méjèèjì ìbòrí náà.+

  • 1 Àwọn Ọba 6:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Lẹ́yìn náà, ó gbé àwọn kérúbù náà+ sínú yàrá inú lọ́hùn-ún.* Ìyẹ́ apá àwọn kérúbù náà nà jáde tí ó fi jẹ́ pé ìyẹ́ apá kérúbù àkọ́kọ́ kan ògiri kìíní, ìyẹ́ apá kérúbù kejì sì kan ògiri kejì, ìyẹ́ apá àwọn méjèèjì wá kanra ní àárín ilé náà.

  • 2 Kíróníkà 3:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ó fi wúrà bo ilé náà àti àwọn igi ìrólé rẹ̀, ó tún fi bo àwọn ibi àbáwọlé rẹ̀,+ àwọn ògiri rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀; ó sì fín àwọn kérúbù sára àwọn ògiri náà.+

  • Ìsíkíẹ́lì 41:17, 18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ó wọn òkè ẹnu ọ̀nà náà, inú tẹ́ńpìlì, ìta àti gbogbo ògiri yí ká. 18 Wọ́n gbẹ́ àwòrán àwọn kérúbù+ àti igi ọ̀pẹ+ sára rẹ̀, àwòrán igi ọ̀pẹ kan wà láàárín kérúbù méjì, kérúbù kọ̀ọ̀kan sì ní ojú méjì.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́