2 Kíróníkà 8:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ní òpin ogún (20) ọdún tí Sólómọ́nì fi kọ́ ilé Jèhófà àti ilé ara rẹ̀,*+ Oníwàásù 2:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Mo ṣe àwọn iṣẹ́ ńlá.+ Mo kọ́ àwọn ilé fún ara mi;+ mo gbin àwọn ọgbà àjàrà fún ara mi.+